Gospel Music

Sola Allison-Obaniyi – “Ayanmo Ife” (Mp3, Video & Lyrics)

Share Post:

Notice: NaijaGoodies.com.ng has pop ads which means a new tab opens once you click, just click close the new tab and continue browsing.


Download and Listen to Sola Allison-Obaniyi – “Ayanmo Ife”

Here an amazing song from the Nigerian soul, folk and gospel singer, and song-writer, who came into limelight with the hit album Eji Owuro.

Hit the play button below as we reminisce and share love with loved ones.


Video

Lyrics

Ololufe wo oju mi
So fun mi p’oo fe mi
Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat’odo Eni to da wa
Ololufe wo oju mi
So fun mi p’oo fe mi

Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat’odo Eni to da wa
O f’imole re fun mi
O f’agbara mi fun o
O f’imole re fun mi
O f’agbara mi fun o
O wa fi idanu si’nu wa
Lati mo ‘fe, lati mo ore
O fi idanu si’nu wa
Lati mo ‘fe, lati mo ore
Owo mi ree, fa mi dani
Ase Oluwa ni

Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat’odo Eni to da wa
Ayo wa ti d’ajose
Ola wa ti d’ajoni
Irin wa ti d’ajorin
Ibanuje ko jina si wa
Wo mi o tun mi wo pel’oju inu
Irin wa laye jo’ra won
Wo mi o tun mi wo pel’oju inu
Irin wa laye jo’ra won
Ayanmo wa j’ayanmo
Loro ife wa se se regi
Ayanmo wa jo ayanmo
Loro ife wa se se regi
Owo mi ree o fa mi dani
Ase Oluwa ni
Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat’odo Eni to da wa
Ko le se ki ija ma wa
Jowo je a jo s’asoye
B’oro ba se bi oro
Jowo fi suuru ba mi se
Ore okan mi pe mi o bi mi
Ogiri wa ko ma a la’nu
Ore okan mi pe mi o bi mi
Ogiri wa ko ma a la’nu
B’aa ba f’imo wa s’okan
Oke oke la o ma lo
B’aa ba f’imo wa s’okan
Oke oke la o ma lo
Owo mi ree yi o fa mi dani
Ase Oluwa ni

Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat’odo Eni to da wa
Ololufe wo oju mi
So fun mi p’oo fe mi
Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat’odo Eni to da wa
Ololufe wo oju mi
So fun mi p’oo fe mi
Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat’odo Eni to da wa
O f’imole re fun mi
O f’agbara mi fun o
O f’imole re fun mi
O f’agbara mi fun o
O wa fi idanu si’nu wa
Lati mo ‘fe, lati mo ore
O fi idanu si’nu wa
Lati mo ‘fe, lati mo ore
Owo mi ree, fa mi dani
Ase Oluwa ni
Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat’odo Eni to da wa
B’afefe idanwo ba fe de
Duro ti mi o girigiri
B’o ti wu k’oorun mu to
Sanmo dudu a wa dandan ni
B’afefe idanwo ba fe de
Duro ti mi o girigiri
B’o ti wu k’oorun mu to
Sanmo dudu a wa dandan ni
Iwenumo ma lo je, ka tun le r’aanu gba si ni
Isoro oni adun ola ni, ayo at’ope lo ma ja si
Owo mi ree yi o fa mi dani
Ase Oluwa ni

Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat’odo Eni to da wa
O f’imole re fun mi
O f’agbara mi fun o
O f’imole re fun mi
O f’agbara mi fun o
O wa fi idanu si’nu wa
Lati mo ‘fe, lati mo ore
O fi idanu si’nu wa
Lati mo ‘fe, lati mo ore
Owo mi ree, fa mi dani
Ase Oluwa ni
Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat’odo Eni to da wa
O f’imole re fun mi
O f’agbara mi fun o
O f’imole re fun mi
O f’agbara mi fun o
O wa fi idanu si’nu wa
Lati mo ‘fe, lati mo ore
O fi idanu si’nu wa
Lati mo ‘fe, lati mo ore
Owo mi ree, fa mi dani
Ase Oluwa ni
Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat’odo Eni to da wa
O f’imole re fun mi
O f’agbara mi fun o
O f’imole re fun mi
O f’agbara mi fun o
O wa fi idanu si’nu wa
Lati mo ‘fe, lati mo ore
O fi idanu si’nu wa
Lati mo ‘fe, lati mo ore
Owo mi ree, fa mi dani
Ase Oluwa ni
Ayanmo ife la je fun ‘ra wa
Lat’odo Eni to da waAbout the author

ADMIN

There's beauty in the struggle - JCOLE!!!

Leave a Comment